عربيEnglish

The Noble Qur'an Encyclopedia

Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languages

Joseph [Yusuf] - Yoruba translation - Ayah 61

Surah Joseph [Yusuf] Ayah 111 Location Maccah Number 12

قَالُواْ سَنُرَٰوِدُ عَنۡهُ أَبَاهُ وَإِنَّا لَفَٰعِلُونَ [٦١]

Wọ́n sọ pé: “A máa jírẹ̀ẹ́bẹ̀ fún bàbá rẹ̀ láti gbà á lọ́wọ́ rẹ̀. Dájúdájú àwa máa ṣe bẹ́ẹ̀.”