The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesMary [Maryam] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 3
Surah Mary [Maryam] Ayah 98 Location Maccah Number 19
إِذۡ نَادَىٰ رَبَّهُۥ نِدَآءً خَفِيّٗا [٣]
(Rántí) nígbà tí ó pe Olúwa rẹ̀ ní ìpè ìkọ̀kọ̀.