The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe Poets [Ash-Shuara] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 130
Surah The Poets [Ash-Shuara] Ayah 227 Location Maccah Number 26
وَإِذَا بَطَشۡتُم بَطَشۡتُمۡ جَبَّارِينَ [١٣٠]
Nígbà tí ẹ bá sì gbá (ènìyàn mú láti fìyà jẹ wọ́n), ẹ̀ ń gbá wọn mú ní ìgbámú aláìlójú-àánú.