The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe Poets [Ash-Shuara] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 169
Surah The Poets [Ash-Shuara] Ayah 227 Location Maccah Number 26
رَبِّ نَجِّنِي وَأَهۡلِي مِمَّا يَعۡمَلُونَ [١٦٩]
Olúwa mi, la èmi àti àwọn ènìyàn mi níbí ohun tí wọ́n ń ṣe níṣẹ́ (aburú).”