The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe Poets [Ash-Shuara] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 203
Surah The Poets [Ash-Shuara] Ayah 227 Location Maccah Number 26
فَيَقُولُواْ هَلۡ نَحۡنُ مُنظَرُونَ [٢٠٣]
Nígbà náà ni wọn yóò wí pé: “Ǹjẹ́ wọ́n lè lọ́ wa lára bí?”