The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe Poets [Ash-Shuara] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 219
Surah The Poets [Ash-Shuara] Ayah 227 Location Maccah Number 26
وَتَقَلُّبَكَ فِي ٱلسَّٰجِدِينَ [٢١٩]
àti ìyírapadà rẹ (fún rukuu àti ìforíkanlẹ̀) láààrin àwọn olùforíkanlẹ̀.