The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe Coalition [Al-Ahzab] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 62
Surah The Coalition [Al-Ahzab] Ayah 73 Location Maccah Number 33
سُنَّةَ ٱللَّهِ فِي ٱلَّذِينَ خَلَوۡاْ مِن قَبۡلُۖ وَلَن تَجِدَ لِسُنَّةِ ٱللَّهِ تَبۡدِيلٗا [٦٢]
(Ó jẹ́) ìṣe Allāhu lórí àwọn tó ti lọ ṣíwájú.[1] O ò sì níí rí ìyípadà kan fún ìṣe Allāhu.