The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThose who set the ranks [As-Saaffat] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 101
Surah Those who set the ranks [As-Saaffat] Ayah 182 Location Maccah Number 37
فَبَشَّرۡنَٰهُ بِغُلَٰمٍ حَلِيمٖ [١٠١]
A sì fún un ní ìró ìdùnnú (nípa bíbí) ọmọkùnrin kan tí ó máa ní ìfaradà.