The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThose who set the ranks [As-Saaffat] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 12
Surah Those who set the ranks [As-Saaffat] Ayah 182 Location Maccah Number 37
بَلۡ عَجِبۡتَ وَيَسۡخَرُونَ [١٢]
Rárá (kò jọra wọn); ìwọ ṣèèmọ̀ (nípa al-Ƙur’ān), àwọn sì ń ṣe yẹ̀yẹ́.