The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThose who set the ranks [As-Saaffat] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 13
Surah Those who set the ranks [As-Saaffat] Ayah 182 Location Maccah Number 37
وَإِذَا ذُكِّرُواْ لَا يَذۡكُرُونَ [١٣]
Àti pé nígbà tí wọ́n bá ṣe ìrántí fún wọn, wọn kò níí lo ìrántí.