The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThose who set the ranks [As-Saaffat] - Yoruba translation - Ayah 135
Surah Those who set the ranks [As-Saaffat] Ayah 182 Location Maccah Number 37
إِلَّا عَجُوزٗا فِي ٱلۡغَٰبِرِينَ [١٣٥]
Àyàfi arúgbóbìnrin kan tí ó wà nínú àwọn tó ṣẹ́ kù lẹ́yìn (láààrin àwọn tí A parẹ́).[1]