عربيEnglish

The Noble Qur'an Encyclopedia

Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languages

Explained in detail [Fussilat] - Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael - Ayah 44

Surah Explained in detail [Fussilat] Ayah 54 Location Maccah Number 41

وَلَوۡ جَعَلۡنَٰهُ قُرۡءَانًا أَعۡجَمِيّٗا لَّقَالُواْ لَوۡلَا فُصِّلَتۡ ءَايَٰتُهُۥٓۖ ءَا۬عۡجَمِيّٞ وَعَرَبِيّٞۗ قُلۡ هُوَ لِلَّذِينَ ءَامَنُواْ هُدٗى وَشِفَآءٞۚ وَٱلَّذِينَ لَا يُؤۡمِنُونَ فِيٓ ءَاذَانِهِمۡ وَقۡرٞ وَهُوَ عَلَيۡهِمۡ عَمًىۚ أُوْلَٰٓئِكَ يُنَادَوۡنَ مِن مَّكَانِۭ بَعِيدٖ [٤٤]

Tí ó bá jẹ́ pé A ṣe al-Ƙur’ān ní n̄ǹkan kíké ní èdè mìíràn (yàtọ̀ sí èdè Lárúbáwá), wọn ìbá wí pé: “Wọn ìbá sì ṣàlàyé àwọn āyah rẹ̀ (kí á lè gbọ́ ọ yé ní èdè wa)? (Bí èdè al-Ƙur’ān bá sì jẹ́ èdè mìíràn) Ṣé (wọn kò tún níí sọ pé, “al-Ƙur’ān jẹ́) èdè mìíràn (Òjíṣẹ́ sì jẹ́) Lárúbáwá!?” Sọ pé: “Ó jẹ́ ìmọ̀nà àti ìwòsàn fún àwọn tó gbàgbọ́ ní òdodo. Àwọn tí kò sì gbàgbọ́, èdídí wà nínú etí wọn ni. Fọ́júǹǹfọ́jú sì wà nínú ojú wọn sí (òdodo al-Ƙur’ān). Àwọn wọ̀nyẹn ni wọ́n sì ń pè (síbi òdodo al-Ƙur’ān) láti àyè tó jìnà.[1]