The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe moon [Al-Qamar] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 53
Surah The moon [Al-Qamar] Ayah 55 Location Maccah Number 54
وَكُلُّ صَغِيرٖ وَكَبِيرٖ مُّسۡتَطَرٌ [٥٣]
Àti pé gbogbo n̄ǹkan kékeré àti n̄ǹkan ńlá (tí wọ́n ṣe) wà ní àkọsílẹ̀.