The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe cloaked one [Al-Muddathir] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 11
Surah The cloaked one [Al-Muddathir] Ayah 56 Location Maccah Number 74
ذَرۡنِي وَمَنۡ خَلَقۡتُ وَحِيدٗا [١١]
Fi Mí dá ẹni tí Mo dá ní òun nìkan (ìyẹn nínú ikùn ìyá rẹ̀).