The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe rising of the dead [Al-Qiyama] - Yoruba translation - Ayah 38
Surah The rising of the dead [Al-Qiyama] Ayah 40 Location Maccah Number 75
ثُمَّ كَانَ عَلَقَةٗ فَخَلَقَ فَسَوَّىٰ [٣٨]
Lẹ́yìn náà, ó di ẹ̀jẹ̀ dídì. (Allāhu) sì ṣẹ̀dá (rẹ̀). Ó sì ṣe é tó dọ́gba jálẹ̀ léèyàn.