عربيEnglish

The Noble Qur'an Encyclopedia

Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languages

The Overthrowing [At-Takwir] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 14

Surah The Overthrowing [At-Takwir] Ayah 29 Location Maccah Number 81

عَلِمَتۡ نَفۡسٞ مَّآ أَحۡضَرَتۡ [١٤]

(nígbà náà ni) ẹ̀mí (kọ̀ọ̀kan) yóò mọ ohun tí ó mú wá (nínú iṣẹ́ ire àti iṣẹ́ ibi).