The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe Overthrowing [At-Takwir] - Yoruba translation - Ayah 15
Surah The Overthrowing [At-Takwir] Ayah 29 Location Maccah Number 81
فَلَآ أُقۡسِمُ بِٱلۡخُنَّسِ [١٥]
Nítorí náà, Èmi (Allāhu) ń fi àwọn ìràwọ̀ tó ń yọ ní alẹ́, tó ń wọ̀ọ̀kùn ní ọ̀sán búra,