The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe Overthrowing [At-Takwir] - Yoruba translation - Ayah 7
Surah The Overthrowing [At-Takwir] Ayah 29 Location Maccah Number 81
وَإِذَا ٱلنُّفُوسُ زُوِّجَتۡ [٧]
àti nígbà tí wọ́n bá so àwọn ẹ̀mí pọ̀ mọ́ra wọn, (ẹni rere pẹ̀lú ẹni rere, ẹni ibi pẹ̀lú ẹni ibi)