The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe Cleaving [AL-Infitar] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 14
Surah The Cleaving [AL-Infitar] Ayah 19 Location Maccah Number 82
وَإِنَّ ٱلۡفُجَّارَ لَفِي جَحِيمٖ [١٤]
Dájúdájú àwọn ẹni ibi yó sì kúkú wà nínú iná Jẹhīm.