The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesDefrauding [Al-Mutaffifin] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 30
Surah Defrauding [Al-Mutaffifin] Ayah 36 Location Maccah Number 83
وَإِذَا مَرُّواْ بِهِمۡ يَتَغَامَزُونَ [٣٠]
Nígbà tí wọ́n bá gba ẹ̀gbẹ́ wọn kọjá, (àwọn olùdẹ́ṣẹ̀) yóò máa ṣẹ́jú síra wọn ní ti yẹ̀yẹ́.