The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe Sun [Ash-Shams] - Yoruba translation - Ayah 10
Surah The Sun [Ash-Shams] Ayah 15 Location Maccah Number 91
وَقَدۡ خَابَ مَن دَسَّىٰهَا [١٠]
Ẹnikẹ́ni tí ó bá fi (ìwà ẹ̀ṣẹ̀) ba ẹ̀mí (ara) rẹ̀ jẹ́, ó mà ti pàdánù.