The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe Sun [Ash-Shams] - Yoruba translation - Ayah 9
Surah The Sun [Ash-Shams] Ayah 15 Location Maccah Number 91
قَدۡ أَفۡلَحَ مَن زَكَّىٰهَا [٩]
Ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣe àfọ̀mọ́ (ẹ̀mí ara) rẹ̀ (níbi ẹ̀ṣẹ̀), ó mà ti jèrè.[1]