The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe Cow [Al-Baqara] - Yoruba translation - Ayah 152
Surah The Cow [Al-Baqara] Ayah 286 Location Madanah Number 2
فَٱذۡكُرُونِيٓ أَذۡكُرۡكُمۡ وَٱشۡكُرُواْ لِي وَلَا تَكۡفُرُونِ [١٥٢]
nítorí náà, ẹ rántí Mi, Kí N̄g rántí yín.[1] Ẹ dúpẹ́ fún Mi, ẹ má ṣàì moore sí Mi.