The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesMuhammad [Muhammad] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 5
Surah Muhammad [Muhammad] Ayah 38 Location Madanah Number 47
سَيَهۡدِيهِمۡ وَيُصۡلِحُ بَالَهُمۡ [٥]
Ó máa fi ọ̀nà (Ọgbà Ìdẹ̀ra) mọ̀ wọ́n. Ó sì máa tún ọ̀rọ̀ wọn ṣe sí dáadáa.