The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe private apartments [Al-Hujraat] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 4
Surah The private apartments [Al-Hujraat] Ayah 18 Location Madanah Number 49
إِنَّ ٱلَّذِينَ يُنَادُونَكَ مِن وَرَآءِ ٱلۡحُجُرَٰتِ أَكۡثَرُهُمۡ لَا يَعۡقِلُونَ [٤]
Dájúdájú àwọn tó ń pè ọ́ láti ẹ̀yìn àwọn yàrá[1], ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ wọn ni kò ṣe làákàyè.