The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe City [Al-Balad] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 20
Surah The City [Al-Balad] Ayah 20 Location Maccah Number 90
عَلَيۡهِمۡ نَارٞ مُّؤۡصَدَةُۢ [٢٠]
Wọ́n máa ti àwọn ìlẹ̀kùn Iná pa mọ́ wọn lórí pátápátá.